Ìròyìn Orílẹ̀-èdè Nàíjiríà

Ìròyìn Ilẹ̀ Àfíríkà

Tillerson-US n fe ajosepo to muna-doko pelu Africa

Akowe agba lorile-ede America Rex Tillerson so pe, orile-ede America ni ajosepo to dan-monran pelu ile Africa, eyi ti yoo je idunu lati tunbo...

Awon agbejoro yoo gbese-le dukia Guptas

Awon agbejoro lorile-ede South African n gbaradi lati gbe igbese lori awon ile-ise meji, eyi to ni-i-se pelu awuye-wuye laarin awon molebi Gupta ati...

Egbe oselu lori aleefa lorile-ede Tanzania jawe olubori.

Egbe oselu Chama cha Mapinduzi (CCM) ti o wa lori aleefa lorile-ede Tanzania jawe olubori ninu atundi  eto idibo sile igbimo asofin , eyi...

Iji lile ni Madagascar sekupa eniyan mokanlelaadota

Iji lile lorile-ede Madagascar lati bi odun mewa sehin sekupa awon eniyan ti o ju mokanlelaadota lo ,awon eniyan mejilelogun di awati,ti ogunlogo si...

Awon agbejoro lorile-ede Uganda tako ayipada ofin

Egbe awon agbejoro  lorile-ede Uganda ni ojo Aje Monday tako ofin  ,eyi ti awon ajafetomoniyan benu ate lu wi pe,eyi yo faye gba Aare...

Eré Ìdárayá

Gomina ipinle kano fofin-de onsere Kannywood

Egbe osere ipinle Kano Guild, ti gboriyin fun Gomina ipinle naa, Dokita Abdullahi Ganduje fun fifofin-de Rahama Sadau, gbajumo onsere obinrin nipinle ohun. Iroyin so...

Ètò Ìlera

Ètò O̩rò̩-Ajé

CIBN, fe mu igberu ba eka ti kii sepo-robi

Egbe ti o n samojuto awon onise isiro lorile-ede Nigeria ati awon asagbeyewo iwe owo lojo-Isegun so pe, ijoba apapo gbodo mu igberu baa...

Nigeria niloo ogooji Bilionu fun ise-akanse irina oju-irin

Minisita fun eto irina lorile-ede Naijiria, Rotimi Amaechi ti so pe, ijoba apapo niloo ogoji bilionu owo Dollars fun ise-akanse irina-oko oju-irin ti o...

Gomina Yobe fowo-si Bilionu kan fawon osise-feyinti

Gomina ipinle Yobe, Alhaji Ibrahim Gaidam, ti fowo si owo ti iye re le ni bilionu kan Naira lati fi sanwo ajemonu awon osise...

Ìròyìn Àgbáyé

Ètò Àgbè̩

Ìròyìn Ìdánilárayá - Ìrìn-àjò Afé̩

Minisita kedun iku Tunde Oloyede

Minisita to n ri si Eto ifitonileti ati Asa lorile-ede Naijria, ogbeni Lai Mohammed ti sapejuwe iku gbajugbaja osere, olukotan ere ori amohun-maworan onipele...

Ipinle merindinlogbon yoo kopa ninu ayeye odun ni Calabar

Ogbeni Gabe Onah to je alaga ajo to n ri si ayeye ara oto fun odun nipinle Cross River ti kede pe lojo Isegun...

Ipinle-Eko seleri lati se ayeye ayajo odun tuntun lona ara

Ipinle Eko ti Gomina Akinwumi Ambode n tuko re, ti so bayii lati se ayeye ayajo ipari odun ati odun tuntun lona ara. Ijoba ipinle...