Aare Zuma Bo lowo Ibo Yiyo Kuro Nipo

Ademola Adepoju.

0
9318
Aare Zuma

Aare orile-ede South Africa, Jacob Zuma ti bo lowo yiyo kuro nipo aare  leyin ibo bonkele eemejo to waye nile igbimo asofin.

Awon egbe alatako ti lero pe egbe African National Congress (ANC) yoo se atileyin fun won lasiko ibo bonkele lati yo aare naa nipo.Esun  iwa ibaje  ti won fi kan aare naa lo fori sopon nigba ti  ibo awon meji-din-nigba gbe ibo  awon alatako to je mẹ́tàdínlọ́gọ́sàn án subu.

Orin ayo ati Idunnu ni awon egbe ANC MPs bere si ni ko, nigba ti won gbo iroyin naa.

Ibo aadota ni awon omo egbe to wa nijoba gbodo di ninu awon òjìlénígba- lé- mesan  to wa nile igbimo asofin ki won to lee yo aare nipo.

 

Ademola Adepoju.

 

LEAVE A REPLY