Ajo ECOWAS sun abewo iko olulaja lo si orile-ede Gambia si ojo Eti.

Abiodun Popoola, Abuja

0
23

Iko olulaja Ajo ECOWAS lo si orile-ede Gambia ti sun irin ajo won lo si orile-ede Gambia lati oni ojo Ru, si ojo Eti ninu atejade kan eyi ti won gbe jade ni ana ojo isegun.

Orile-ede Gambia n koju laasigbo oloselu lehin ti Aare Yahya Jammeh ko lati gbe ipo fun eni ti o jawe olubori ninu eto idibo si ipo aare to waye lorile- ede naa ni ojo kinni osu kejila odun to koja ,ngba ti alatako re Adama Barrow jawe olubori..

Iko olulaja naa eyi ti aare orile-ede Liberia, Ellen Johnson Sirleaf, yoo koja si orile-ede Gambia lati ro Aare Yahya Jammeh   lati gbe ijoba silefun eni ti o jawe olubori .

 

Fi èsì sílẹ̀