Ajo EU yoo gbalejo apero lori Syria ati awon agbegbe re

0
18

Federica Mogherini to je oloye lori aba fun Ajo EU ti ile Geesi ni ajo naa yoo gbalejo apero lori ekun Syria ati agbegbe re ni ojo karun un osu kerin odun yii.

O ni apero yii yoo fun won laaye lati wo ibi ti ise de duro lori oro alaafia ajo isokan agbaye ti United Nations. Bakan naa ni won yoo wo esi apero ti London to waye lodun 2016.

O ni:Ä lero pe apero ti brussels ni ojo karun un osu kerin yii yoo satileyin to ye fun ajo isokan United Nations lori eto oselu. Ni afikun pelu ijiroro lori ona atisatileyin lori ojo iwaju ile Syria ati awon agbegbe re.

Awon mii ti won yoo ko pa ni awon ajo agbaye, ijoba ile Germany, Kuwait, Norway, Qatar ati Britain.

SHARE

Fi èsì sílẹ̀