Ajo Isokan Agbaye benu ate lu ado-oloro ti won ju ni Damascus

0
22
General Assembly Seventieth session Informal Dialogues with Candidates for the Position of Secretary-General: Mr. Antonio Guterres Panel L to R: Mr. Antonio Guterres, former United Nations High Commissioner for Refugees Mr. Mogens Lykketoft, President of the seventieth session of the General Assembly. Ms. Catherine Pollard, Under Secretary-General for General Assembly and Conference Management

Antonio Guterres to je akowe agba ajo isokan agbaye ti a mo si United Nations ti benu ate lu jiju ti won ju ado oloro ni Damascus lojo abameta to koja. O ni awon agbesunmomi naa gbodo jiya to ye lataari ikolu olu ilu Syria.

Ogbeni Stephane Dujarric to je agbenuso salaye ninu atejae to fi sit ape :ïsele yii dun akowe agba pupo, pea won kan ko naani emi awon eniyan. O kedun pelu awon ti oro kan ninu awon to je arinrinajo. O di dandan ki owo tea won ti o ju ado oloro lu ara ilu”

Ikolu yii se iku pa awon aadota eniyan shite ile Iraqi ti awon ogofa eniyan tun farapa gege bi ile ise ijoba apapo ile Iraq se so. Won ni awon arinrinajo naa n sabewo si ile mimo to wa ni Babal-Saghir to je ite to tobi ju ni Syria.

Ijoba ni ki awon ile mii dekun sise atileyin fawon onise ibi agbesunmomi bii orile ede Turkey, Saudi Arabia, Qatar ati awon ile okeere mii.

 

SHARE

Fi èsì sílẹ̀