Àrùn onígbá-méjì ń tànkálè̩ ni orílè̩ èdè Mozambique

0
20

O le le̩gbe̩run kan eniyan ni orile̩ ede Mozambique ni arun onigba-meji ti ba finra ni eyi to ti se iku pa eniyan meji leyin aroda ojo. Ile ise ijoba to n mojuto eto ilera ni eyi yoo tubo di wahala tijoba ko ba tete gbe igbese to ye.

Arun yii je eyi to n waye pelu omi ti ko dara. O bere si ni ran lati Maputo to je olu ilu Mozambique lo si ekun meta ninu awon ekun metala lodun yii gege bi Benigna Matsinhe to je igbakeji oludari eto ilera apapo se safihan re.

O ku agbegbe mokandinlogun ti o wa ni bebe ki arun yii be sile nibe laipe ojo ti a ko ba tete gbe igbese to ye.

Eni kan ti ku ni Maputo, enikeji ku ni ariwa iwo oorun ni Tete. Ogbele to sele ni guusu ile Afrika lodun to koja saaju igba ojo Mozambique naan ii se. Losu to koja ni iji ja ni eyi to fa omiyale to gbemi o le ni eniyan meje.

Arun onigba-meji yii n fa ki eeyan maa yagbe ki o sit un maa bi nigba kan naa.

SHARE

Fi èsì sílẹ̀