Àwo̩n agbébo̩n ko̩lu o̩ko̩-irànwó̩ ní orilè̩-ède South-Sudan

Ademola Adepoju ati Tobi Sangotoye

0
24

Ajo igbimo agbaye fun eto awon arinrin ajo ti a mo si International Organization Migration (IOM) ti so wi pe awon eniyan meji lopadanu emi won, ti awon meta si farapa yanayana nibi ikolu to waye ni orile ede South Sudan, nigba ti awon agbebon koju ija si oko iranwo.
Awon ajo isokan orile-ede agbaye ti da si awon ilu kan kan ti awon ikolu yii ti waye ti won si so wi pe awon eniyan ti o le ni milionu marun un ni won ku oju owon ounje leyin awon isele yi
Oogun be sile ni Orile-ede South Sudan leyi to si da iyapa sile ti o mu awon eniyan ti o to milionu meta ni ye lati padanu emi ati ohun ini won sinu isele buruku naa
Ikolu naa sele ni o ku die ka de Yirol, ni aarin ilu Juba, ni bi ti awon osise to n seto iranlowo ti n koju aisan onigba-meji be sile tele. Gege bi atejade lati odo awon IOM, won ni oko aju morin yii ni won fojusun bi o se n dari si ilu Yirol, nibiti awon agbebon ti kolu ikan lara awon oko yii, ti awon meji si salaisi, ti awon miran si farapa, gegebi adari naa seso
A gbo wi pe Ko si iwe idanimo Kankan lati fi to pase awon janduku naa. Besi ni, awon onisegun Medecins Sans Frontieres (MSF) so wi pe ile iwosan won ni Wau Shilluk ni won baje yanayana lasiko rogbodiyan ti o sele yi. Gegebi ti oga ile iwo son naa seso Abdalla Hussein Abdalla, o ni gbogbo ogun won pata ni won ti kolo, ti won si baa ile iwoson naa je yanayana Ni ibere oseyi lagbo wipe awon aagbebon tuti koo awon eniyan mejo kan si apamo ti won sise pelu
Ogun abele yii bere ni odun 2013 nigbati aare Salva Kiir, ti o wa lati ilu Dinka, daa igbakeji re duro Riek Machar lati ilu Nuer
Awon omo oogun Machar’s, awon akoju won lati ilee sudan, ni ojooru Thursday ni won benu atelu awon omo oogun tuntun miran ti ogagun to sese kowe fise sile ni bere odun yi se adari won
Atejade ti awon omo oogun Machar’s ni ilu Equatoria fi sita ni pe, won siti mu daa Ogagun feyinti Thomas Cirilo Swaka loju pe ko fokan tan awon pe kosi wahala
Ooya awon igbimo SPLA IO lenu bee sini lee kan naa won si ko lati gba oro ogagun Thomas Cirilo to soo pe awon omo ogun re ti se tan, won si ti fi dahun loju pe awon wani baabe fun ijoba tuntun re
Aaro ogagun Thomas lati tun imoo re pa lati ma kosowo awon Salva Kiir’s allies ni ilee naa, ti ero re je lati daa arin won ru

SHARE

Fi èsì sílẹ̀