Àwo̩n agbébo̩n ní orílè̩-èdè South-sudan pa òpò ènìyaǹ

0
38

Awon agbebon ni orile ede South-sudan ti pa awon eniyan mejidinlogbon, ti won si ko awon omo sa lo ni ilu ti o sun mo Ethiopia.
Awon osise si so pe isele yi ni o fihan bi ogun abele ile Sudan se bere tele. Agbenuso fun ijoba, Chol Chany so pe irede naa bere lojo aiku ati ojo Aje, bere ni Gambella Gog ati jor ni eyi to pa aala pelu ekun Borma ni South Sudan.
Ogun abele ile yii ti bere lati odun 2013 ti aare Salva Kiir ti da igbakeji re duro lenu ise, iyen Reik Machar ni osu kejila odun 2013. Ija eleyameya ti pin orile ede naa ni eyi ti o to milionu meta awon eniayn ti won ti sa asala lo fun emi won.
O to milionu kan eniyan ti won n satipo ni awon orile ede bii Ethiopia, Uganda, Kenya ati Sudan to sunmo won. Eru ti n baa won alase ki ikolu yii ma lo yapa lo si awon orile ede to sunmo South sudan laipe. Chany ni o to ogorun un kan omode to ti pada si ethipoia ti awon to ku si wa ni owo awon ajinigbe.

Ademola Adepoju ati Tobi Sangotola

SHARE

Fi èsì sílẹ̀