Trump ni Egypt loun a koko sabewo si nile Adulawo

Aare orile-ede America, Donald Trump, ti kede pe orile-ede Egypt loun a koko sabewo si nile Adulawo. Barack Obama ti Trump gba ipo lowo...

Ile-iwe Tanzania wole pada leyin ijamba-oko to seku pa eni marundinlogoji

Ile iwe tawon elede geesi to wa ni Arusha ni orile-ede Tanzania ti wole pada lojo Aje leyin ti oko-ofurufu ti gbe awon meta...

Aare tuntun ile Faranse yoo se-abewo si awon omo-ogun lorile-ede Mali

Aare tuntun fun orile-ede Faranse Ogbeni Emmanuel Macron, yoo se abewo si awon omo-ogun ti won se ise akanse ipetusaawo lorile-ede Mali lopin ose...

Omiyale je ki won ti ile-iwe pa ni Tanzania

Awon alase ile Tanzania ti ti awon ile-iwe to wa ni erekusu Zanzibar ni Tanzania pa lataari omiyale to sele leyin ojo arooroda to...

Olori egbe-oselu alatako Zambia da oko awon olopaa pada

Olori egbe oselu alatako lorile-ede Zambia, Ogbeni Hakainde Hichilema ko lati wo oko awon olopaa ti o ye ki o gbe e pada si...

Eto inu ifamieye-danilola fawon olorin nile Adulawo ti jade

Ajo isokan ile Adulawo ti a mo si African Union Commission, (AUC) ti siso loju eegun igbese eto inu fifi ami eye da awon...

Awon o̩mo̩-ogun ilè̩ Faranse s̩eku pa awo̩n ajijagbara ile̩ Mali

Awon omo-ogun orile-ede Faranse ti seku pa awon ogun eniyan lara awon ajijagbara ni ibugbe won ti won farapamo si lorile-ede Mali ati Burkina...

Omo ogun ijoba ile South Sudan gba awon opopona ilu Juba

Awon ologun Ijoba orile-ede South Sudan ti gba opopona ilu Juba leyin ti o ti gba isakoso olu ile ise iko ologun awon alatako...

Tunisia yan minista omiran fun eto isuna-owo.

Olori ijoba orile-ede Tunisia, Youssef Chahed ti fi elomiran ropo minisita fun eto isuna owo lorile-ede naa leyin ti awon alatako ninu egbe oselu...

Opo binu bi olopaa Angola se kolu awon Akanda-eda to n fehonuhan

Fonran aworan kan to safihan bi awon olopaa Angola se kolu awon alaabo-ara to n fehonuhan ti ru ibinu sookan aya opolopo awon eniyan...
- Advertisement -

Latest article

Ijoba Naijiria yoo mu edinwo ba ipese iresi

Ijoba orile-ede Naijiria n gbero lati gbe igbese ti yoo mu edinwo goboi ba ipese iresi lorile-ede yii. Adele aare, Ojogbon Yemi Osinbajo lo...

Omo ile Afrika di giwa Ajo eleto ilera lagbaaye

Omowe Tedros je eni akoko ninu omo ile Afrika ti yoo di ipo oga agba ajo eleto ilera ninu ajo isokan orile ede agbaye...

Awon olopaa kede eni to ju ado-oloro Manchester

Oruko afurasi ti won gba pe o ju ado-oloro to dun ni Manchester ni awon olopaa kede ni Salman Abedi.  Iko agbofinro Greater Manchester...