Naijiria yoo gbe Kasuu to to bilionu meje owo dola lo si America

Orile-ede Naijiria ti n duna-dura pelu ile itaja nla Walmart to je eyi to to bi julo lorile-ede America lori kiko Kasuu ti won...

Ijoba ipinle Delta ati aladani kan towobo adehun ogun-milionu dola lori ogbin ope

Ijoba ipinle Delta ti buwolu iwe adehun pelu ile ise aladani Norsworthy Investment Limited kan lori ise akanse isowo ope ati epo ninu saare...

Minista fun eto inawo parowa pe ki awon eniyan kopa ninu eto IITA

Minista fun eto inawo, Kemi Adeosun, ni orile-ede yii yoo jere nipa kikopa ninu eto tuntun ti banki ile Adulawo, African Development Bank, gbe...

Naijiria bere ilana ofin lori kiko isu lo sile okeere

Omowe Vincent Isegbe to je alakoso ile ise ijoba to n ri si ayewo ohun ogbin ti ni o ti seese bayii fawon agbe...

Dongara ro awon eniyan Naijiria lati tubo seto ogbin

Agbenuso fun ile igbimo asofin kekere lÁbuja, Honorebu Yakubu Dogara ti parowa fawon olokowo gbogbo lorile-ede yii lati tubo mojuto eto ogbin lalada nla...

Dangote na bilionu kan dola lati gbin iresi

Iko onisowo Dangote ti kede pe oun n na bilonu kan owo dola ile America sinu ogbin iresi nipinle marun un ki ounje le...

South Africa Kore agbado leyin ogoji odun

Orile-ede South Africa nireti lati kore agbado lopo yanturu leyin ogoji odun. Ikore yii n bo leyin oda to ti ba won finra pupo....

Adele-Aare se-filole ise-akanse olopo-bilionu naira ti omi Zaria

Ojogbon Yemi Osinbajo to n dele gege bi aare fun orile-ede Naijira lowolowo ti se ifilole ise akanse ipese omi to to aadojo milionu...

Adamawa murasile de igba ogbin ti yoo so eso rere

Ijoba ipinle Adamawa ni ariwa oke oya Naijiria ti selelri lati satileyin to ye fawon agbe lasiko ogbin todun yii nipa pipese awon ero...
- Advertisement -

Latest article

Pinnick: Papa Isere Godswill Akpabio Nilu Uyo Si Duro Gege Bi Papa Isere Akoko...

Aare egbe to n risi boolu afesegba lorile-ede Naijria, Amaju Pinnick ti sọ pe papa isere Godswill Akpabio ti o wa ni ilu Uyo,...

Adele-Aare Yoo Wa Nibi Ayeye Ibura Fun Aare Orile-Ede Rwanda

Loni ojo eti(Friday) adele-aare orile-ede Naijiria, ojogbon Yemi Osinbajo yoo wa nibi ayeye ibura fun olori orile-ede Rwanda ogbeni Paul Kagame. Ayeye ohun yoo waye...

Ijoba Orile-Ede Naijiria, Ati Egbe Oluko Tile-Eko Giga-Fafiti(Asuu) Yoo Bere Ipade Ijiroro Laarin Ose...

Ijoba orile-ede Naijiria ati egbe oluko ile-eko fafiti (ASUU) ti fenuko lati bere eto iduna-dura lori iyanse-lodi ti o n lo lowo ni awon...