Ipinle Taraba fe safihan ohun alumooni re ni Germany

Awon omo igbimo ati alamojuto eka iwakusa ipinle Taraba ti yan Gomina Darius Isiaku to n tuko ipinle Taraba lati lo safihan awon alumooni...

Naijiria se ifilole igbimo alamojuto akosile owo nina

Ijoba orile ede Naijiria ti se ifilole igbimo alamojuto akosile bi won se n nawo nilu Abuja. Ajo yii ni yoo maa samojuto akosile...

Naijiria bere ajosepo pelu CNN lori irinajo-afe

Ajosepo elenu meta ti bere laarin ile ise ijoba apapo to n risi eto ifitonileti- iroyin ati asa ni orile-ede Naijiria, ati eka irin-ajo...

Naijiria ri ere to le ni bilionu mejidinlogoji ninu asuwon re

Ogbeni Ahmed Idris to soju Abileko Kemi Adeosun to je minista Naijiria fun eto inawo salaye fawon oniroyin pe o le ni otalenirinwo bilionu...

Minista seleri lati fopin si owo ori lorisiirisii ni Abuja

Ile ise ijoba apapo to n risi oro owo ori nilu Abuja to je olu ilu Naijiria ti a mo si Federal Capital Territory...
- Advertisement -

Latest article

Ijoba Naijiria yoo mu edinwo ba ipese iresi

Ijoba orile-ede Naijiria n gbero lati gbe igbese ti yoo mu edinwo goboi ba ipese iresi lorile-ede yii. Adele aare, Ojogbon Yemi Osinbajo lo...

Omo ile Afrika di giwa Ajo eleto ilera lagbaaye

Omowe Tedros je eni akoko ninu omo ile Afrika ti yoo di ipo oga agba ajo eleto ilera ninu ajo isokan orile ede agbaye...

Awon olopaa kede eni to ju ado-oloro Manchester

Oruko afurasi ti won gba pe o ju ado-oloro to dun ni Manchester ni awon olopaa kede ni Salman Abedi.  Iko agbofinro Greater Manchester...