EPL: Liverpool fagbahan Manchester City ninu ifigagbaga topin ose

Iko agbaboolu Liverpool FC se gudugudu meje ohun yaya mefa ninu ifigagbaga ti o waye lopin ose, ni papa isere Anfield lojo aiku (Sunday),...

Esi ifesewonse idije NPFL ti saa 2017/2018

Eyi ni esi ifesewonse idije boolu afesegba torile-ede Naijiria ti saa 2017/2018, ti o waye lopin ose ni kikun (NPFL): Kwara United 0-2 Niger...

Germany fowosi lilo ero igbalode fonran fun idari ifesewonse

Awon ojogbon adari ifesewonse ti o kaju osuwon lorile-ede Germany ti fowosi lilo Ero-igbalode Fonran VAR ninu idije boolu agbaye to n bo lona...

Russia 2018: Ifesewonse olorejore yoo muwa gbaradi sii

Akonimoogba agba fun iko agbaboolu Super Eagles, Gernot Rohr ti fi idunnu re han pupo lasiko iforowanilenuwo pelu awon akoroyin, eyi waye lataari idaniloju...

Coutinho buwolu iwe-isise po iko agbaboolu Barcelona

Philippe Coutinho agbaboolu iko Liverpool FC ti buwolu iwe-isise po olodun marun-un pelu iko agbaboolu Barcelona ti o n dije ninu idije La Liga...

Stoke city FC gba-ise lowo Mark Hughes

Ni bayii, opin ti deba ise Mark Hughes ninu iko agbaboolu Stoke city FC, leni ti o je akonimoogba agba iko naa, lataari aise...

Joshua yoo figagbaga pelu Alexander Povetkin

Ni bayii, o seese kii Anthony Joshua ko waako pelu Alexander Povetkin oluja omobibi orile-ede Russia, ti o ba ko lati ni adehun ifigagbaga...

Murray yoo se ise-abe fun ipalara ti o ni

Andy Murray omobibi ile-biritiko ti so bayii pe, o seese kii oun se ise abe fun ipalara ti oun ni lese, leyin ti atamatase...

EPL: Manchester City, Palace, Westham-United jawe olubori

Iko agbaboolu Manchester City bere saa odun tuntun lona ti o fakoyo, leyin ti iko ohun fagba-han iko agbaboolu Watford pelu ami-ayo meta (3-1),...

Naijiria se ipo kewa ninu idije EPL

Orile-ede Naijiria fiida-laale ati ni paapajulo awon agbaboolu ti orile-ede ohun ti pese lolokan-o-jokan ti n won kopa ninu idije EPL lorile-ede England. Iroyin so...
- Advertisement -

Latest article

Ile-ise NDE se idanileko fun awon odo lorile-ede Naijiria.

Ile-ise to n pese ise lorile-ede Naijiria National Directorate of Employment (NDE) ti beere idanileko fun awon odo ,eyi ti won ko ni ise...

Ile-ifowopamo AfDB se ileri iranlowo nla-nla fun orile-ede Naijiria.

Ile-ifowopamo to n risi idagbasoke ile Afirika African Development Bank, (AfDB),ti se ileri aleekun iranwo owo  fun orile-ede Naijiria pelu aleekun iye owo ti...

Ijoba ipinle Bayelsa mu igbeeru deba eto oro aje re.

Ijoba ipinle Bayelsa lojo eti Friday so wipe igbeeru ti de ba eto oro aje ni ipinle naa latari idokowo kekeke ,eyi ti o...