Italy so abere-ajesara di kanpa leyin ti igbona be sile

Orile-ede Italy ti pase fun awon eniyan ile naa pe o di dandan ki won gbe omo won jade fun abere-ajesara tabi ki won...

Ijoba Naijiria pase ayewo Ebola fawon Ero to n wole

Ijoba orile-ede Naijiria ti pase fawon osise eleto ilera lati bere ayewo ni kikun fun gbogbo awon arinrinajo to n wo Naijiria bayii fun...

Yemen kede ilu ko-fararo lori arun onigbameji to be sile

Orile-ede Yemen ti kede ilu ko fararo lataari arun onigbameji to be sile ni Sanaa to je olu ilu Yemen ni eyi ti o...

Ijoba Naijiria n fe ki awon eniyan tubo nifura lori Ebola

Ijoba orile-ede Naijiria ti parowa fawon olugbe orile ede yii lati tubo nifura lori oro Ebola. Ojogbon, Adewole Isaac, to je minista fun eto...

Jimoh:- NAFDAC yoo gbogunti ayedeeru ohun-eelo nipa imo ero

Ajo ijoba apapo Naijiria to n risi oro ohun jije ati oogun lilo (NAFDAC) ti ni won yoo safikun imo lorisirisii ona ero igbalode...

Aisha Buhari sayewo fawon asatipo

Iyawo Aare orile-ede Naijiria, abileko Aisha Buhari tepele mo Pataki ki awon obinrin maa sayewo ago ara won ki won le maa gbe igbe...

Somalia sisepo pelu ajo WHO lati gbogun ti arun onigba-meji

Ajo ilera agbaye ati orile ede Somalia ti bere ajosepo lati gbogun ti arun onigbameji ni ekun naa. Won bere ifilole ipolongo lori arun...

Abere Ajesara fun Polio yoo bere leekeji- Komisona

Komisona fun eto ilera nipinle Oyo ni Ijoba ipinle Oyo ti pari ise pe ki pinpin abere ajesara fawon omo owo bere leekeji ni...

Ayajo Aisan Iba: Ipinle Kano fe ko ibudo ilera tuntun

Ipinle Kano ti pinnu lati sagbekale ibudo ilera tuntun si woodu orinlelogorin o le ni irinwo to wa ni ipinle naa. Komisona fun eto...

Naijiria bere ise lori ipese awon ibusun to ni egboogi ninu

Dawnets to je ile ise kan nilu Aba nipinle Abia lorile ede Naijiria ti bere ise lori sise awon ibusun to ni egboogi ninu...
- Advertisement -

Latest article

Ijoba Naijiria yoo mu edinwo ba ipese iresi

Ijoba orile-ede Naijiria n gbero lati gbe igbese ti yoo mu edinwo goboi ba ipese iresi lorile-ede yii. Adele aare, Ojogbon Yemi Osinbajo lo...

Omo ile Afrika di giwa Ajo eleto ilera lagbaaye

Omowe Tedros je eni akoko ninu omo ile Afrika ti yoo di ipo oga agba ajo eleto ilera ninu ajo isokan orile ede agbaye...

Awon olopaa kede eni to ju ado-oloro Manchester

Oruko afurasi ti won gba pe o ju ado-oloro to dun ni Manchester ni awon olopaa kede ni Salman Abedi.  Iko agbofinro Greater Manchester...