Adele-aare Naijiria yoo bere ijiroro pelu awon osise ijoba

Ojogbon Yemi Osinbajo to je Adele-aare to n tuko Naijiria lowolowo yoo jiroro pelu awon osise ijoba nipele lorisiirisi lojo Ru. Ogbeni Laolu Akande,...

Adele-Aare Naijiria tewogba isuna 2017 lowo ile-igbimo asofin-agba

Ojogbon Yemi Osinbajo to je Adele aare Naijiria bayii ti tewogba eto isuna fun odun 2017 kuro lowo awon omo ile igbimo Asofin agba...

NDDC ti na bilionu mejidinlogoji fun idagbasoke ipinle Bayelsa

Ile ise ijoba apapo to n mojuto oro awon ekun ti a ti n wa epo robi ni Naijiria ti a mo si: The...

Moji Olaiya, gbaju-gbaja osere Nollywood jalaisi

Awon egbe osere ni Naijiria tun sofo ogbontarigi mii ninu awon osere lataari iku Mojisola Olaiya, eni to je omo odun mejilelogoji. Ile iwosan...

Abuja, olu-ilu Naijiria ati agbegbe re san gbese awon agbasese

Owo to to le ni bilionu metadinlogota owo naira ni won san fun awon agbasese lori awon ise akanse ti won se lorisiirisi nilu...

Ijoba Naijiria pase ayewo Ebola fawon Ero to n wole

Ijoba orile-ede Naijiria ti pase fawon osise eleto ilera lati bere ayewo ni kikun fun gbogbo awon arinrinajo to n wo Naijiria bayii fun...

Ezeemo:- Agbelero awon ohun eelo se pataki sidagbasoke oro-aje

Ogbeni Godwin Ezeemo to je okan lara awon onile ise nla to n ro awon ohun eelo ni Naijiria ti parowa fawon eniyan orile-ede...

Awon asoju-sofin ni ki ise oko-oju-irin kari ekun kookan

Awon asofin agba lorile-ede Naijiria ti fi dandan sii pe ki ise to n lo lowo lori ipese oko-oju-irin lorile–ede yii wa kaakiri ekun...

Naijiria gboriyin fun ajo agbaye U.N. fun iranlowo lori igbogun-ti boko-haram

Orile-ede Naijiria ti gboriyin fun ajo agbaye, United Nations, lori akitiyan won lati sise papo fun gbigbogun ti awon boko haram pelu ona iranlowo...

Oshodi-Glover parowa fawon olopaa lati tubo sise sii

Igbakeji oga agba olopaa patapata loril-ede Naijiria to wa fun ekun iwo oorun guusu, Agboola Oshodi-Glover, ti parowa fawon olopaa lori ona iba-awon ara...
- Advertisement -

Latest article

Ijoba Naijiria yoo mu edinwo ba ipese iresi

Ijoba orile-ede Naijiria n gbero lati gbe igbese ti yoo mu edinwo goboi ba ipese iresi lorile-ede yii. Adele aare, Ojogbon Yemi Osinbajo lo...

Omo ile Afrika di giwa Ajo eleto ilera lagbaaye

Omowe Tedros je eni akoko ninu omo ile Afrika ti yoo di ipo oga agba ajo eleto ilera ninu ajo isokan orile ede agbaye...

Awon olopaa kede eni to ju ado-oloro Manchester

Oruko afurasi ti won gba pe o ju ado-oloro to dun ni Manchester ni awon olopaa kede ni Salman Abedi.  Iko agbofinro Greater Manchester...