Trump sabewo sile Isreal pelu eto aabo to lagbara

Aare ile America, Donald Trump yoo sabewo sile Isreal ati ekun Palestine ninu irinajo re to n se lowo si aarin gbungbun ila oorun...

Macron yan awon obinrin fun ida meji minista tuntun re

Aare tuntun ti won yan lorile-ede Faranse, Emmanuel Macro, ti siso loju eegun ipinnu re lati ma segbe fun awon kan ninu yiyan awon...

South Korea fe bere ibanisoro tuntun pelu North

Orile-ede South Korea salaye lojo Ru to koja pe oun yoo bere ona ibanisoro tuntun pelu ti Ariwa re. Aare Moon Jae lo m...

Aare tuntun ile Faranse yoo se-abewo si awon omo-ogun lorile-ede Mali

Aare tuntun fun orile-ede Faranse Ogbeni Emmanuel Macron, yoo se abewo si awon omo-ogun ti won se ise akanse ipetusaawo lorile-ede Mali lopin ose...

Yemen kede ilu ko-fararo lori arun onigbameji to be sile

Orile-ede Yemen ti kede ilu ko fararo lataari arun onigbameji to be sile ni Sanaa to je olu ilu Yemen ni eyi ti o...

Orile-ede Faranse bura fun Aare Macron

Loni ni won se ibura fun Aare Emmanuel Macron to jawe olubori ninu eto idibo to waye fun ipo aare lorile ede Faranse ni...

Ado oloro inu apo dun ni Rome

Ado oloro kan dun ni orile-ede Roomu leba ile ifiweranse aarin gbungbun ile naa loni. Awon oniroyin ile Italy salaye pe ko fee si...

Germany bere ajosepo pelu China lori idagbasoke ile Afrika

Minista orile-ede Germany fun ipese iranlowo fun idagbasoke, Gerd Mueller, ni orile-ede Germany ati China ti bere ajosepo lati da oro ile won po...

Aare South-Sudan yan olori iko omo ogun miran

Aare ile South Sudan ti fi ogagun agba miran lati iran to kere nile naa dipo Ogagun Paul Malong to je olori awon omo...

Aare adiboyan tuntun fun France setan lati gbogunti eleyameya

Emmanuel Macron, won sese dibo yan ti seleri lati gbogunti iwa eleyameya gbogbo ni eyi to gba pe o n yo ile Faranse lenu....
- Advertisement -

Latest article

Ijoba Naijiria yoo mu edinwo ba ipese iresi

Ijoba orile-ede Naijiria n gbero lati gbe igbese ti yoo mu edinwo goboi ba ipese iresi lorile-ede yii. Adele aare, Ojogbon Yemi Osinbajo lo...

Omo ile Afrika di giwa Ajo eleto ilera lagbaaye

Omowe Tedros je eni akoko ninu omo ile Afrika ti yoo di ipo oga agba ajo eleto ilera ninu ajo isokan orile ede agbaye...

Awon olopaa kede eni to ju ado-oloro Manchester

Oruko afurasi ti won gba pe o ju ado-oloro to dun ni Manchester ni awon olopaa kede ni Salman Abedi.  Iko agbofinro Greater Manchester...