CBN yoo tubo da owo-idokowo seto oro-aje bi owo-ifipamo se di ogbon bilionu dola bayii

0
16

Awon igbese banki Naijiria, CBN, ti fihan pe ijoba n gbe igbese to ye lati rii pe owo-idokowo inu banki si banki n lole bi o se seleri. Eyi ri bee lataari igbese lati tun da owo-idokowo mii si lose yii gege bi owo-ifipamo ile okeere se di ogbon bilionu owo dola bayii.

Afihan lati itakun agbaye banki Naijiria, CBN fihan pe o ti n lewo diedie bere lati ojo karun un osu kinni odun 2017. Lile ti owo yii n le see ko je lataari odiwon iye owo epo robi to ti gberi soke leyin adehun ajo OPEC ati awon ti kii se omo egbe ajo OPEC.

Ogbeni Isaac Okiriafor, to je adele oludari eka banki Naijiria to n risi eto iroyin ni banki Naijiria CBN, ni ijoba ko ni je ki awon eniibi ba gbogbo igbese naa je.

Bakan naa lo ni CBN yoo fiya to to je eni ti palaba re ba segi lori owo oja inu owo-idokowo.

Bilionu kana ti irinwo milionu owo dola ni CBN ti da sinu owo-idokowo forex lose to koja ni onidokowo owo nlanla atawon keekeeke.

SHARE

Fi èsì sílẹ̀