Chuck Berry, Ògbóǹtarigì òǹko̩rin onígìtá s̩aláìsí láàdó̩rún o̩dún

0
16

Chuck Berry, Ogbontarigi onkorin onigita ti gbogbo aye gba gege bi baba orin alajo-si-jelenke ku lomo aadorun odun. Berry korin fun odindin aadorin odun ni eyi to gbe orisirisi awo jade. Lara awon orin re ni ti akole roll over Beethoven ati Johnny Goode.

O gba ami eye ayeraye ti Grammy lodun 1984, o wa lara awon ti won gba wole lodun 1986 si agbole awon oga agba ninu orin alajo-si-jelenke.

Awon olopaa nipinle Missouri nile America jeri si iku re. Ojo Abameta lodin die laago kan ni won kiyesi pe o ti dagbere faye.

SHARE

Fi èsì sílẹ̀