Egbe Taekwando fun Naijiria ti mu ojo eti fun eto idibo

Tobi Sangotola ati Ademola Adepoju

0
169

Egbe ere idaraya Taekwando fun orile-ede Naijiria (NTF) ti soro lori eto idibo iyansipo awon omo egbe fun ajo naa. Eyi ti yoo waye lojo Eti ni ilu Abuja.

Akowe agba fun egbe NTF, Ogbeni Taiwo Oriss, lo so eyi di mimo ni ilu Abuja, ti o si wi pe, eto idibo naa ni won o se ni ipele keji ni papa isere Abuja National Stadium.

O tesiwaju pe gbogbo ipinle ni orile-ede Naijiria lo fi awon asoju won ranse ti won yoo kopa nibi eto idibo ohun

Akowe agba ohun so naa ni olukopa, akonimoogba tabi adari ere idaraya  ni aaye lati  gba tabi kopa ninu eto idibo ohun.

O tenumo pe, awon asoju yii lo gbodo ti wa ninu iwe ifunilowo ni ipinle ti won ba n soju fun.

“O ni ki gbogbo ipinle ri I daju pe won fi awon asoju won ranse si ile iforukosile lati se ohun gbogbo to to ati eyi to ye.

 

Tobi Sangotola ati Ademola Adepoju

 

LEAVE A REPLY