IBASEPO TO DANMORAN LAARIN ORILE-DE FIJI ATI ORILE-EDE ETHIOPIA

Abiodun Popoola, Abuja

0
21

Idunnu orile-ede Ethiopia ni lati ni ibasepo to danmoran pelu orile-ede Fiji ni orisirisi ona leyin ti asoju Pataki fun orile-ede Ethiopia se abewo si orile-ede naa ni ojo aje to koja .
Oludamoran Pataki si olori ijoba orile-ede Ethiopia, Tedros Adhanom Ghebreyesus so fun ile ise iroyin eyi ti o je ti ijoba ,lorile-ede Fiji so wipe orile-ede naa se ipinnu rere lati se ifilole ile ise ijoba orile-ede naa lorile-ede Ethiopia.
Sisi ille ise naa yoo mu ki ibasepo to dan moran wa laarin orile-ede mejeeji, pelu awon omo egbe ajo isokan ile Afrika gege bi asoju ijoba orile-ede Ethiopia se so.
Ibeere ibasepo idokowo ati idasile ile ise nlanla je ohun elo ti yoo mu ibasepo to da moran wa laarin awon mejeji eredi ni yi ti orile-ede Fiji se ko ile ise igbase naa.
Abewo Ghebreyesus si orile-ede Fiji pelu ipade ijiroro pelu olori ijoba Voreqe Bainimarama eyi ti o tenumo wipe eyi yoo umu ibasepo to danmoran wa laarin won., pelu idaniloju wipe orile –ede Ethiopia yoo se atileyin fun orile-ede Fiji lati kopa ninu idije dupo si ipo aare igbimo awon egbe oselu ni ilu Bonn ,lorile-ede Germany ninu odun ti awa yi
Orile-ede Fiji ati orile-ede Ethiopia se ifenuko ibasepo ti o dan moran lati osu kini odun 2011.

Fi èsì sílẹ̀