Ibugbamu ado oloro se iku pa opolopo eniyan ni Afghanistan.

0
20

O to ogbon eniyan to doloogbe ninu ikolu to waye ni Kabul ni Afghanistan nibi ti ogorin eniyan ti farapa yanyan. Ni Kandahar nitosi ibugbe gomina ni eniyan mejila ti jalaisi ti opolopo fi farapa bii asoju UAE si Afghanistan.

Ikolu Taliban

Ekun Helmand ni asekupani kan ti ju ado oloro sile itura ti awon eniyan Pataki n lo ti o si se iku pa awon meje lasiko ti ero po to n jade lati ile itura naa.

Aare Ashraf Ghani ti bura lati sawari awon onise ibi naa ni eyi ti awon Taliban ti gba pea won ni won wa nidi re.

Okan lara awon asofin ni ekun Herat, Rahima Jami naa farap ninu ikolu naa. Zabi to je okan lara awon eso to wa nibe ni ikolu akoko selel nita gbongan naa nibi ti won gbe oko ayokele kan si .

Ahmad wali, to je oga olopaa ekun keje ni ikolu naa sunmo enu ona fafiti America.

Fi èsì sílẹ̀