Ibugbamu ado oloro ti won fi dode Asofin lorile-ede Afghanistan, se opolopo eniyan lese

Abiodun Popoola

0
26

Ibugbamu ado oloro eyi ti won fi dode omo ile igbimo asofin lorileede Afghanistan nilu Kabul ni ojo Ru sokunfa ifarapa opolopo eniyan ati Asofin naa pelu.
Fakori Behishti, ti o je omo ile igbimo asofin lati ekun Banyan ati omo re farapa yanayana ninu ifarapa naa gege bi awon eleto aabo ni ile asofin naa se so
Kosi enikeni ti o ti so wi pe awon ni won wa nidi ikolu naa, eyi to ba oko ayokele asofin naa je, ti ferese awon ile itaja ti o wa nibe ba je lopolopo
Irufe isele yii waye ni ose ti o koja latowo afemisofo kan ti o seku pa eniyan meje otooto.

Fi èsì sílẹ̀