Iko agbaboolu Super Eagles goke si ninu ipo ate tuntun ajo FIFA lagbaye

Tobi Sangotola.

0
195
Iko agba-boolu Super Eagles

Iko agba-boolu Super Eagles ti orile-ede Naijiria, ti goke si lati  ipo mokandinlogoji si ipo mejidinlogoji ninu ipo ate tuntun ajo FIFA lagbaye ti o sese jade lana ode yii.

Pelu gi goke si ohun, iko agba-boolu Super Eagles sibe won si wa ni ipo kefa ninu ate tuntun ile Afrika

Bakan naa, iko agba-boolu Egypt wa ni ipo marundinlogbon lagbaye, ti won si wa ni ipo kini ni ile Afrika.

Beeni, orile-ede Congo Dr, Senegal, Tunisia ati Cameroon tele ra won ni sise-n-tele.

Ni bayii, orile-ede Brazil ti bo si ipo kini, nigba ti orile-ede Germany si gba ipo keji lagbaye.

Ate tuntun ajo FIFA nile Afrika

  1. Egypt
  2. Congo Dr
  3. Senegal
  4. Tunisia
  5. Cameroon

 

Tobi Sangotola.

LEAVE A REPLY