Ile-ejo giga julo ni Naijiria ni ki Okezie maa ba ise lo nipinle Abia

0
146

Loni ni Ile ejo to ga julo lorile-ede Naijiria, pase pe ki gomina ipinle Abia, Okezie Ikpeazu maa sise lo gege bii gomina ti won dibo yan nipinle naa ninu eto idibo to koja.

Ile ejo pase naa lori eri pe won fa Okezia kale lona ti o to ati eyi to ye pelu ibamu pelu ilana ofin fun egbe oselu Peoples Democratic Party (PDP).

A o maa salaye kikun lori iroyin yii laipe.

LEAVE A REPLY