Ile ejo to gaju lorile-ede Gambia sun eto igbejo tako eto idibo si osu kaarun un odun

Abiodun Popoola, Abuja

0
25

Adajo agba lorile-ede Gambia Emmanuel Fagbenle, so wi pe ile ejo to gaju lorile-ede naa ko ni le joko gbejo ejo Aare Yahya Jammeh eyi ti o pe lati fagile eto idibo to waye orile-ede naa titi osu kaarun un odun yii.

Adajo agba ti o je omo orile-ede Naijiria ti yoo je adele ile ejo naa Onogeme Uduma, ko le ni anfani lati joko igbejo naa titi opin osu karun un odun yii.

Aare Yahya Jammeh  ti o je omo odun mokanlelaadota gba abajade esi idibo sugbon eyi ti o ko jale leyin eto idibo naa.

Ko i ti si afihan wi pe aare Yahya Jammeh yoo kuro lori aleefa ni ojo kejidinlogun osu kinni odun yii.

Aare Adama Barrow, ti won dibo yan eyi ti won se ibura fun sugbon aare Jammeh ko lati gbe ijoko sile ,eyi ti awon ologun nse atileyin fun.

Awon olori orile-ede ni apa iwo oorun ile Afrika  eyi ti aare Muhammadu Buhari ndaari,yoo koja si orile-ede Gambia ni ojo eti Friday.

Sugbon Ogbeni Jammeh benu ate lu awon igbese yi  eyi ti o se apejuwe re gege bi aheso ati atojubo.

Eyi ni igba ikeji ti won yoo sun eto igbejo naa siwaju lataari awon adajo eyi ti ko to lati joko fun eto  igbejo naa. latari eyi, won ti yan awon adajo lati ile okeere ti won muleti won.

Fi èsì sílẹ̀