Ile-iwe Tanzania wole pada leyin ijamba-oko to seku pa eni marundinlogoji

0
348

Ile iwe tawon elede geesi to wa ni Arusha ni orile-ede Tanzania ti wole pada lojo Aje leyin ti oko-ofurufu ti gbe awon meta pere tori ko yo ninu ijmba oko to sele naa lo si orile-ede America fun itoju.
Akekoo mejilogbon ati oluko meji pelu awako oko naa lo gbemi mi nigba ti oko naa yi kuro loju popo ni agbegbe Karatu ni ariwa ile Tanzania lasiko ti won n ko awon akekoo na a lo se idanwo.
Awon meta tori ko yo ti won n gba itoju ni– Doreen Elibariki (13), Saida Awadh (11) ati Wilson Tarimo (11). Lojo Aiku ni ajo Onigbagbo aranilowo kan ni Siouxland ni Tanzania ati ajo Tanzania fun eto ilera ati eto eko seto lati gbe won lo sile America.
Ijoba ti seto igbaninimoran fawon akekoo to wole pada lojo Aje nitori won tile iwe naa pa lati gba ti ijamba oko naa ti sele. Ephrahim Jackson, to je olori ile iwe naa salaye fawon oniroyin pe Äsiko yii bani ninuje gidi fun gbogbo akekoo ati oluko ile-iwe yii. Eto igbaninimoran di dandan sugbon a si n tepeple mo ifokannsin awujo eni. Adura na la si maa maa gba si Olorun.
Awon ebi ti oro kan ni won ti seleri lati sanwo gbama-binu fun leyin ti ijoba seto isinku awon marundinlogoji to salaisi ninu isele naa. Awon Asofin orile-ede naa ti fun won ni milionu lona ogorun un owo ile naa, eyi to tumo si eedegberin le ni merinle logoji egberun owo dola fawon ebi oloogbe.

LEAVE A REPLY