Jimmy Kimmel yoo tun gbalejo Oscars fun todun 2018

  0
  201

  Awon to n seto igbalejo Oscars fun todun 2018 ti ni Ogbontarigi Adanilaraya nibi eto, Jimmy Kimmel, ni yoo tun se alaga iduro nibi eto ohun fodun to m bo. Won ni won fenuko lori ipinnu yii lataari bi Jimmy se fi ogbon agba ati iriri to koja egbe abewu seto ohun lodun yii.

  Ojo kerin, osu keta odun to m bo ni eto naa yoo waye ni Dolby Theatre. Igba akoko ti Kimmel se alaga iduro ni todun yii, eyi to ti fi ogbon yanju asise to sele nigba ti won sesi si apo iwe Warren Beatty ati ti Faye Dunaway gbe si ara won ti won si lo tun sesi kede La La Land gege bii fiimu to dara ju fodun naa.

  Ile ise amohunmaworan ABC to n gbe eto Osacars safefe naa ni Kimmel ti n sise. Michael De Luca ati Jennifer Todd naa ni won yoo jo sise papo fun eto naa. Eto Oscars ni eto to gbayi julo to safihan ise awon osere nibi ti ifami eye da ni lola fun orisirisi ti n waye.

  Eto naa ati Kimmel ni awon eniyan lorisiirisii gboriyin fun eto naa gbe ounje fegbe gba awo bo. Eto Oscars todun yii ni o ni ero iworan to kere julo lati odun 2008 ti eto naa ti bere ni eyi to le ni milionu mejilelogbon ero iworan ti wo.

  LEAVE A REPLY