LMC pàs̩e̩ ìtanràn ìyà tótó̩ je̩ Ikhana fún ìwà ìbàjé̩ tó hù

0
20

League Management Company to je ajo to n mojuto isele ati itoju awon to nii se pelu idije boolu alafesegba ni Naijiria ti pase owo itanran egberun lona igba naira fun akonimoogba fun awon egbe agbaboolu Kano Pillars lapa ariwa Naijiria lataari pe o se lodi si ofin NPFL.
Lasiko ti idije n waye laarin Plateau United ati Kano pillars ni Akonimoogba Ikhana huwa ti ko to rara nipa sisoro alufansa sawon to seto idije naa nita gbangba.

SHARE

Fi èsì sílẹ̀