Naijiria yoo fi awon agunbaniro kun awon to n janfani adojutofo eto-ilera

0
775
Awon agunbaniro yoo lanfani silera adojutofo NHIS

Awon odo Naijiria ti won n sinru ile baba won fun odun kan ni won yoo fi kun awon ti yoo maa je anfaani eto adojutofo ilera ti a mo si NHIS bayii. Minista fun eto ilera, Ojogbon Isaac Adewole lo soe eyi di mimo leyin ipade awon amusese leka ijoba apapo to waye nile ijoba lojo Ru ni eyi ti adele are, ojogbon Yemi Osinbajo salaga le lori.

O ni ipinnu lati fi awon agunbaniro kun awon ti yoo maa janfaani yii waye lati dena iku ojiji ti ko nidi to n sele siwon laarin odun kan ti won fi n sin ile baba won yii. “Eyi yoo je ki won ni eto ilera to ye larowoto won lasiko yii, awon odo wa yoo ni anfani seto ilera yii kaakiri orile-ede Naijiria ni”

Naijiria towobo iwe adehun pelu UNFPA

Minista fun eto ilera tun ni ipade awon amusese ijoba apapo ti fowosi pe ki a tun adehun wa towobo pelu ajo isokan agbaye to n pese owo iranwo fun igbese inu ikaniyan lori tita ati rira awon ohun eelo ifetosomobibi ati ise to ro mo o.

Ijoba Naijira ni ilana ofin pe ki won maa pin in lofe kaakiri orile-ede yii ni eyi ti yoo wa lodun merin sii 2017 si 2020”

O nijoba Naijiria yoo tubo maa pese awon ohun eelo idaabobo ati ifetosomobibi kaakiri orile-ede yii.

LEAVE A REPLY