NEPAD Nigeria n fe ki eto adojutofo-ilera di mimo kariaye

0
9425

Abileko Gloria Akobundu to je oludari agba ajo NEPAD to wa fun idagbasoke ile Adulawo ni Naijiria ti pe fun ise ti yoo je ki awon eniyan orile-ede yii tubo nimo kikun lori ise awon adojutofo ninu eto ilera ki erongba ijoba lori sise agbekale eto iranlowo ilera naa le di mimuse

Abileko Alobundu salaye Pataki eto ilera adojutofo yii pe gbogbo eniyan orile-ede yii lo nilo re lati gbogun ti isoro ilera kariaye

Fun awon aladani

Adari ajo NEPAD naa ki ijoba Naijiria ku ise lori sise agbekale NHIS. O ni bi won se fi eto naa lole fawon aladani pelu naa je igbese lojuna to dara ki o le kari fun gbaogbo eniyan .

 

LEAVE A REPLY