O̩ba ilè̩ Morocco Kí Ààre̩ Buhari kú oríire

0
16

O̩ba Mohammed kefa lori aleefa orile ède Morocco ti ki Aare Mohammodu Buhari kaabo pada sile layo̩ leyin irinajo re fun isnimi ati ilera ni London.
O̩ba yii fi idunu re han lasiko to pea are lori aago fun irufe ona ikini kaabo ti awon eniyan Naijiria se fun Aare.
O ni eyi fihan pea are yii je eyi ti aye n fe ti awon eniyan re si tewogba. O̩ba yii s̩abewo si Naijiria losu kejila lodun to koja. Aare Buhari dupe lowo Oba ile̩ Moroocco fun atileyin re ati ajosepo to dan moran to wa laarin Naijiria ati Morocco.
Lojo ‘Bo to koja ni awon eekan ninu ijoba Naijiria ati Morocco se ipade papo ni eyi to dun moa won olori mejeeji.

SHARE