Omiyale je ki won ti ile-iwe pa ni Tanzania

0
321
Omiyale ni Tanzania

Awon alase ile Tanzania ti ti awon ile-iwe to wa ni erekusu Zanzibar ni Tanzania pa lataari omiyale to sele leyin ojo arooroda to ro ni agbegbe naa. Minista fun eto eko lekun naa, Riziki Pemba Juma, ni o di dandan kijoba gbe igbese yii lati doola emi awon akekoo ki won ma lo ko sinu ijamba.

Ojo naa ba ile ati ona je pupo. O le ni egberun aadota le ni oodunrun awon akekoo ni ekun naa ni Tanzania ti oro ohun kan. Juma ni “awon akekoo to n se idanwo asekagba tiwe mewaa yi n se idanwo won lo”

Bakan naa niroyin wa pe ojo arooroda to n ro lapa ila oorun ile Adulawo ti seku pa awon eniyan merinla ti awon egberun kan abo eniyan mii ti di alainile lori nitosi orile ede Kenya.

LEAVE A REPLY