Omo orile-ede Somalia ati omo orile-ede Canada di minisita amojuto irin ajo lorile-ede Canada

Abiodun Popoola, Abuja

0
23

Ahmed Hussen, ti o je agbejoro ati ajafetomoniyan, ti o si fi orile-ede Somalia se ibujoko, ti orile-ede Canada ti yan gege bi minisita fun eto irinajo lo si ile okeere, awon asafogun ati jije ojulowo omo orile-ede naa.

Ogbeni Ahmed Hussen, ni o je omo ile igbimo asofin orile-ede Canada nilu Toronto gege bi asoju rgbr oselu Liberal Party lorile-ede Canada.

Yiyan sipo yi ni Olri Ijoba orile-ede Canada Justin Trudeau kede ni ojo isegun Tuesday latari awon atunto eyi to nwaye ninu isakoso ijoba naa.

Eto ibura fun gbogbo awon eniyan wonyi yoo waye loni.  Ogbeni ni o koja si Ahmed Hussen  orile-ede Canada lodun 1993 ,ti o si fidi kale si ilu Regent Park ,nibi ti o tin sise sin awon ara ilu.

Bkanna ni o je olori egbe awon omo orile-ede Somalia lorile-ede Canada lati ma ja fun eto awon omo orile-ede Somalia lorile-ede Canada.fun ibasepo to danmoran,

O kawe gboye ninu eto eko itan ni fafiti York, ti o si kawe gboye imo ofin ni fafiti Ottawa.

Ogbeni Ahmed Hussen ni o je olufo ede geesi, Somali ati ede Swahili daradara.

Gege bi ipo ti o dimu

  1. Akosile aba ki ko awon asatipo ,egeberun maarundinlogbon lati orile ede Syria ni awon osu to nbo losi ibi atipo won gege bi igbiyanju ijoba orile-ede Canada.
  2. Lati se akosile ati aleekun anfaani eto ilana olododun lati fun awon obi awon ti won wa lati orile-ede miran lati wo orileede Canada
  3. Aleekun anfaani fun awon omo iya awon olugbe orile-ede Canada ni anfaani lati wa si orile-ede naa.
  4. Alekun ojo ori awon omo ti won nilo lati itoju latowo awon obi won lati odun mokandiklogun si mejilelogun,lati le fun awon omo won lati wa baa awon obi won lorile-ede Canada/
  5. Akosile aba fun awon oko tabi aya tuntun lati woo rile-ede Canada.

 

Fi èsì sílẹ̀