Omooba Saudi Yoo fi ẹgbẹ̀rin owo Dola Dokoowo lorile ede Egypt

Ademola Adepoju.

0
805
Alwaleed bin Talal

Omooba orile ede Saudi Alwaleed bin Talal , yoo fi owo to le ni egberin dola(612.70 million pounds) dokoowo ki igberu lee ba ile igbafe saa merin to wa ni Sharm el-Sheikh pelu ajosepo  ile ise Talaat Moustafa. Sahar Nasr to je  Minisita  fun eto idokoowo lorile ede Egypt lo so eleyii lojo Aje.

Oloro Alwaleed yoo tun da ile itura tuntun meji sile ni al-Alamein, nigberiko Mediterranean ati Madinaty   to wa  ni orile Egypt , Nasir lo so eleyii ninu iwe atejade kan.

Alwaleed ni ile itura ati igbafe  to le ni ogoji lorile ede Egypt, pelu awon mejidinlogun to n ko lowo.

Ninu osu kefa ni orile ede Egypt gbe ofin kan jade lati fi aaye gbe awon to fe da okoowo sile , ki won si tun fi aaye gba awon olokoowo to ti fi igba kan fi orile ede naa sile lasiko rogbodiyan oselu  ti orile ede naa  la koja lodun 2011.

 

Ademola Adepoju.

LEAVE A REPLY