Orílè̩-èdè Amé̩ríkà fi ohun èèlò ogun ráns̩é̩ sí orílè̩-èdè South Korea

0
22

Orile-ede Amerika ti bere si ni ko awon ohun ija ogun re lo si orile-ede South Korea gege bi agbenuso awon ologun orile-ede naa ti so ni ojo aje Monday lati tako igbese orile-ede North Korea eyi ti o n tesiwaju ninu erongba ohun ose ogun re.

Ohun ose ogun yi ti won n pe ni Gray Eagle Unmanned Aerial Systems (UAS) eyi ti o n bo lati orile-ede South Korea wa lara ilana kiko ile ise ipese ohun elo ija ogun naa pelu opolopo iyapa ti o wa ninu iko oloogun naa. Gegebi ogbeni Christopher Bush se so ninu atejade re.

Orile-ede North Korea ti se ayewo ohun amusagbara re yi leemeeji otooto, eyi ti o je eyi to lagbara ju lati ibeere odun yi biotilejepe Ajo isokan orile-edve Agbaye gbe ofin ifiyajeni le lori.

Ni ose to koja asoju orile-ee Amerika si inu  Ajo isokan orile-ede Agbaye United Nations UN Nikki Haley so wipe orile-ede Amerika nse agbeyewo ilana ati igbese orile-ede North Korea ati wipe gbogbo eto lo nlo ni sepe.

Orile-ede Amerika ko iko oloogun re ati awon ohun elo oogun lo si orile-ede South Korea bi o tile je pe orile-ede China n tako gidigidi.

Ohun elo ogun orile-ede Amerika yi le sise koja orile-ed North Korea, woo rile-ede China.

Bakanna ni orile-eede Russia nkominu lori igbese orile-ede Amerika yi eyi ti o le sokunfa gbigbe-gidina erongba re lori ile Korea.

SHARE

Fi èsì sílẹ̀