Orí́lè̩-èdè Ethiopia kéde o̩jó̩ mé̩ta fún ò̩fò̩ ilè̩ rírì tó s̩e̩lè̩

0
17

Ijoba ile̩ Ethiopia kéde is̩o̩fo̩ fun odindin o̩jó̩ me̩ta lataari ile riri to se iku pa opolopo eniyan ni olu ilu re, Adsis Ababa. Losan ojo’ru ni won so asia kale nigba ti iye awon to gbemi mi nibi ile riri naa di o kere tan eniyan mejilelaadorin.
O le ni eniyan metadinlogun ti won yo oku won jade nitosi ile ijosin Abune Aregawi nibi ti won ti n josin. Lojo isegun ni awon olopaa ati awon osise ibe ni won ti to eniyan mejilelogorin.
Ile riri naa ba opolopo ilea ti dukia je ni eyi to so awon eniyan to po ti won n gbe agbegbe ibe di alaini ounje ati alinile lori bayii.
Orile ede Ethiopia je okan lara awon orile ede ile Afrika ti oro aje n dagba.

SHARE

Fi èsì sílẹ̀