Orílè̩-èdè Turkey be̩nu àte̩ lu Àjo̩ EU lórí ìpolongo orílè̩-èdè Netherlands

Popoola Abiodun

0
33

Ile ise ijo̩ba to n risi o̩ro̩ ilè̩ òkeere lorile-ede Turkey ti ko ipe awon osise Ajo isokan ile Europe lati jawo ninu atileyin ipolongo oloselu orile-ede Netherlands.

O se apejuwe ipe naa gege bi eyi ti ko niye lori latowo akowe fun ile okeere ninu Ajo isokan ile Europe .Federica Mogherini ati komisona fun isodipupo ninu ajo naa, Johannes Hahn.

Ipe yi waaye leyin ti orile-ede Netherlands fofin de awon minisita lorilede Turkey, ti o sir o won lati jawo ninu ipolongo fun ipade fifi edun okan ara ilu han ti yoo waaye saaju eto idibo lorile-ede Netherlands.

Ipade mimo ero inu ara ilu yi yoo sokunfa arinyanjiyan ti yoo tubo fun aare orile-ede Turkey Recep Tayyip Erdogan ni agbara si.

Ni idahun si ipe orile-ede Netherlands ,orile-ede Turkey fofinde asoju orile-ede Netherlands lati pada si orile-ede naa,ti won si gbegile ijiroro oloselu pelu awon ti won lamilaaka ninu eto oselu.

Aare Recep Tayyip Erdogan. Fesun kan orile-eede Netherlands wipe o nlo ilana orile-ede Germany.

Ipolongo waaye lati se iranlowo fun orile-ede Turkey ninu Ajo EU lati fohunsokan ninu eto idibo mimo okan ara ilu ti yoo waaye ni ojo kerinla osu keerin odun yi lati se aleekun agbara aare ajo naa.

SHARE

Fi èsì sílẹ̀