Orile-ede Faranse bura fun Aare Macron

0
259

Loni ni won se ibura fun Aare Emmanuel Macron to jawe olubori ninu eto idibo to waye fun ipo aare lorile ede Faranse ni aafin Elysee. Macron, to je omo odun mokandinlogoji di aare ile Faranse to kere julo lojo ori.

Eto ifilole naa bere igba otun fun isejoba tuntun lorile ede naa.

Ekunrere iroyin n bo laipe.

LEAVE A REPLY