Rafsanjani, Aare orile ede Iran nigba kan ri doloogbe

0
21
Aare ile Iran tele

Aare fun ile Iran tele, Akbar Hashemi Rafsanjani, jalaisi nile iwosan kan ni Tehran nibi ti won gbee lo lojo aiku to koja.

Atejade ti won fi sita fihan pe aisan okan lo pa a. Rafsanjani doloogbe lomo odun mejilelogorin. O je eniyan Pataki nigba aye e ni orile ede Iran. O je alaga igbimo to n mojuto ipari aawo laarin awon oloselu ati awon igbimo alamojuto to ye.

Hossein Marashi  to je oluranlowo fun aare naa to tun je okan lara awon molebi re salaye pe ile iwosan ni Tehran lo ti doloogbe.

Fi èsì sílẹ̀