Senegal fi awon agbaboolu meedogbon to maa koju Naijiria han

0
23

Akonimoogba fawon agbaboolu alafesegba ile Senegal, Aliou Cisse ti foruko awon iko merindinlogbon to maa koju Naijiria ninu idije ibaraenisere to maa waye ni ojo ketalelogun osu keta odun yii ni London sita.
Lara won ni agbaboolu fun Liverpool, Sadio Mane, ti Everton ti a mo si Idrissa Gana, ati Opa Nguette Metz to ti figba kan gba boolu fun ile Faranse.
Anderlecht To je Kara Mbodji naa ti wa nikale lai naani orunkun to n yoo lenu. Mohammed Diame to n gba boolu fun Newcastle ti kede ifeyinti re.
Orile ede Senegal bori de idije ipo keta ninu idije ere boolu alafesegba tile Adulawo ni orile ede Gabon eyi ti Naijiria ko kopa ninu re.
Papa isere The Hive to je tile egbe agbaboolu Barnet ni yoo ti waye. Awon akopa ni:

Adele: Abdoulaye Diallo, Khadim Ndiaye, Pape Seydou Ndiaye
Oludena boolu sawon ile: Kalidou Koulibaly, Kara Mbodj, Saliou Ciss, Lamine Gassama, Moussa Wagué, Zargo Toure, Adama Mbengue, Cheikh Mbengue
Alatako: Idrissa Gana Gueye, Cheikhou Kouyate, Pape Alioune Ndiaye, Salif Sané, Henry Saivet, Alfred Ndiaye, Cheikh Ndoye
Awon to n gba niwaju: Sadio Mané, Diao Baldé Keïta, Mame Biram Diouf, Ismaîla Sarr, Opa Nguette, Moussa Sow, Famara Diediou, Babacar Khouma Gueye.

SHARE

Fi èsì sílẹ̀