South Korea fe bere ibanisoro tuntun pelu North

0
545

Orile-ede South Korea salaye lojo Ru to koja pe oun yoo bere ona ibanisoro tuntun pelu ti Ariwa re. Aare Moon Jae lo m gbero fun ilana ofin onigun-meji to nii se pelu ofin ese ati ona iforowero pelu alajogbele re lori awon ohun ija oloro fun ogun.

Orile-ede North Korea ko fipamo pe oun n sise lori ohun ija oloro eyi to lagbara lati fi gbogun ti orile ede America. Bakan naa lo ti ko lati gbo si ase awon orile ede to ku lenu bii china to je ore kan soso ti won ni.

Lojo Aiku to koja lo fihan pe pun ko ni gba imoran Kankan lori ohun elo ija oloro re yii gege bi igbimo ajo agbaye to n risi eto aabo se so. Lee Duk-haeng to je agbenuso fun ile ise ijoba ti the South’s Unification Ministry ni Öun to se Pataki si wa bayiii ni sisi oju opo ibanisoro laarin South Korea ati North Korea. Ile ise wa ti ye gbogbo awon igbese to seese wo sugbon a ko tii fenuko si eyi ti a maa lo”

Lodun to koja ni awon orile-ede mejeeji ko lati ba ara won soro mo lataari jiju ti awon North Korea ju ohun elo oloro gege bi ipinnu Pyongyang lati ti ibudo ile ise apa ariwa pa. Awon North Korea ni igbese awon di dandan lati fi fopin si iwa ibi ile America.

Lose to koja ni won dibo yan Moon ninu eto idibo to koja. Awon iko Moon fun iforowero pelu America ti gbera lo si Washington loni. Awon naa ni Ogbontagiri oniroyin ile South Korea Hong seok Hyun nibi ti won yoo ti jiroro lori oro North Korea.

Hong ni South Korea ko tii gba oro adimu lenu ile America boya Seoul yoo sanwo fun awon ero igbalode to n fopin si ohun eelo ija oloro ti won gbe lo si ta Seoul.

Orile-ede America gba pe oun yoo ro China lati fofin de ipinnu ajo agbaye lori north Korea ni kete to ba ti fopin si ohun ejo ila oloro naa.

Aare Donald Trump tile America ti ni ki won dawo ayewo awon ohun ija oloro naa duro ni kiakia. O ni ki won sora losu yii nitori eyi le sokunfa aigboraeniya nla laarin North Korea.

 

LEAVE A REPLY